Ìjọ Christ Embassy sọ wí pé àwọn kò gbóríyìn fún Bọla Tinubu Ka ìròyìn l'ẹkunrẹrẹ nínú linki yìí 👉🏾
Ìjọ Christ Embassy sọ wi pé àwọn kò gbóríyìn fún Bọla Tinubu. Wọ́n ní irọ́ gbáà ni ọ̀rọ̀ yìí ti àwọn ènìyàn ń pín kiri lórí ẹ̀rọ ayélujára.Wọ́n ní ó ṣọ wí pé Tinubu jẹ́ arákùnrin tí ó wà láti ilé Pharaoh, tí ó rí ojú rere Ọlọ́run.
Gẹ́gẹ́bí bí ahesọ yìí ṣe wí, Tinubu, ẹni tí ó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀rí, ẹni tí àwọn ènìyàn ti ṣe inúnibíni sí ni yóò mú ìlọsíwájú dé bá Nàìjíríà.
“Oríṣiríṣi ìdènà ni àwọn ènìyàn ṣe fún-un. N kò tíì ṣe alabapade ẹni tí àwọn ènìyàn p’ẹgan rẹ̀ tó báyìí. Àmọ́, ó borí àwọn ìdènà. Fún bíi ọdún mẹ́jọ tí ó ran Buhari lọ́wọ́ láti jaweolubori, ojú arákùnrin náà rí àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwà biobakiobulẹsẹ. “Gbogbo àwọn alágbára ni ó ṣe alátakò rẹ̀, ju gbogbo ẹ lọ, ó borí. Arákùnrin yìí jẹ́ ẹni tí ó wá láti ilé Pharaoh. Ó mọ bí nkan ṣe rí, ó sì jẹ àǹfààní nínú rẹ̀. Ó mọ ohun tí ènìyàn gbọ́dọ̀ ṣe nígbà tí ó bá di ọ̀rọ̀ ìtàn. Ojú rẹ̀ ti rí.
Nigeria Latest News, Nigeria Headlines
Similar News:You can also read news stories similar to this one that we have collected from other news sources.
Christ Embassy: No bi us write di viral statement wey dey praise Tinubu | TheCableLoveworld Inc., di main kompani wey get Christ Embassy International, don comot hand for di viral statement wey dey praise Bola Tinubu.
Read more »
APPLY: US embassy seeks qualified administrative assistant in Abuja | TheCableThe United States embassy in Nigeria is seeking to employ a qualified candidate for the role of an administrative assistant in Abuja.
Read more »
The Rise Of Bola Ahmed TinubuBola Ahmed Tinubu has never lost an election he contested in, whether it was for the Senate seat, governor or president. And in every election, opponents were
Read more »
Actor Jim Caviezel & Angel Studios Drive Awareness To End Child Trafficking With Sound of FreedomAmerican actor, Jim Caviezel (The Passion of Christ, The Count of Monte Christo) and Angel Studios (creators of The Chosen, David animation) are driving
Read more »
Nigerian Government Declares Public Holiday For May 29 Swearing In | Sahara ReportersThe President Muhammadu Buhari-led Nigerian government has declared Monday, May 29, the Inauguration Day of the “president-elect”, Bola Tinubu as a work-free day for workers nationwide. Recall that the Inspector-General of Police (IGP), Usman Alkali Baba had also said that the May 29 date set for the inauguration of the Bola Tinubu was sacrosanct. The police chief had said this while addressing journalists in Abuja. He had described people making threats regarding the inauguration of Tinubu as unpatriotic brands, saying the police would defend Nigeria’s democracy.
Read more »
I Picked An Igbo Catholic As My Chief Security Officer To Douse Islamisation Claims – ‘Vice-President-Elect’, Kashim Shettima | Sahara ReportersThe “Vice-President-Elect”, Kashim Shettima, has said that he was a child of necessity, while allying claims that he and his principal, Bola Tinubu, have an agenda to islamise Nigeria. “I was a child of necessity, there is no Islamisation agenda,' he said, adding that 'Asiwaju Bola Tinubu is a Muslim who is married to a Christian, not only a Christian but a pastor in the Redeemed Christian Church of God'. SaharaReporters reports that Tinubu a former governor of Lagos State South West Nigeria is of Muslim faith.
Read more »