Ǹjẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Senegal sọ pé ìwà orílẹ̀ èdè Faransé sí Senegal kò dára?

Nigeria News News

Ǹjẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Senegal sọ pé ìwà orílẹ̀ èdè Faransé sí Senegal kò dára?
Nigeria Latest News,Nigeria Headlines
  • 📰 thecableng
  • ⏱ Reading Time:
  • 43 sec. here
  • 2 min. at publisher
  • 📊 Quality Score:
  • News: 21%
  • Publisher: 80%

Nigeria's independent online newspaper

Tí ó bá ń lo àwọn ohun ìgbàlódé ibaraẹnise ní wákàtí mejidinlaadọta sẹhin, ó ṣeé ṣe kí ó ti wo fídíò tí ó safihan Bassirou Diomaye Faye, ẹni tí orílẹ̀ èdè Senegal yàn laipẹ gẹ́gẹ́bí Ààrẹ níbi tí ó ti ń sọ̀rọ̀ sì orílẹ̀ èdè Faransé .

“Àsìkò tó tí orílẹ̀ èdè Faransé gbọ́dọ̀ dẹkùn ijokolenilọrunmọlẹ, kí wọn sì fòpin sí ìwà irẹnijẹ. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ìyà, irẹnijẹ, ikonilẹru ti fa ìyà. Ó tó gẹ́,” báyìí ni ẹni kan ṣe sọ nínú fídíò yìí. Láti ìgbà tí ó ti fi fídíò yìí síta, àwọn ènìyàn ẹẹdẹgbẹta ló ti fẹ́ràn ọ̀rọ̀ náà, àwọn ènìyàn ọgọrùn-ún mẹta àti mẹtalelọgbọn ló ti pín in, àwọn ènìyàn ọgbọ́n àti méjì ló ti sọ̀rọ̀ nípa ẹ, àwọn ènìyàn ẹgbẹ̀rún ní ọ̀nà ogún ni wọn ti wòó.

We have summarized this news so that you can read it quickly. If you are interested in the news, you can read the full text here. Read more:

thecableng /  🏆 2. in NG

Nigeria Latest News, Nigeria Headlines

Similar News:You can also read news stories similar to this one that we have collected from other news sources.

Nigeria's President Tinubu Arrives Late at Inauguration Ceremony in SenegalNigeria's President Tinubu Arrives Late at Inauguration Ceremony in SenegalNigeria's President, Bola Tinubu, arrived late at the inauguration ceremony of the newly elected President, Bassirou Diomaye Faye, in Senegal. This was revealed by an international journalist on Twitter.
Read more »

Learn democracy from Senegal, TMG tells NigeriaLearn democracy from Senegal, TMG tells NigeriaTransition Monitoring Group (TMG) has called on Nigeria and other West African nations to adopt Senegal’s democratic principles as a blueprint for advancement.
Read more »

Nigeria can learn lesson from Senegal’s presidential election, says AtikuNigeria can learn lesson from Senegal’s presidential election, says AtikuAtiku Abubakar has said Nigeria has a huge lesson to learn from Senegal whose recent elections saw the emergence of Bassirou Faye
Read more »

The abducted children of Kuriga and other stories, By Reuben AbatiThe abducted children of Kuriga and other stories, By Reuben AbatiPremium Times - Nigeria'bs leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria
Read more »

Leadership and accountability, By Toyin FalolaLeadership and accountability, By Toyin FalolaPremium Times - Nigeria'bs leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria
Read more »

Tinubu approves Renewed Hope Infrastructure Development FundTinubu approves Renewed Hope Infrastructure Development FundPremium Times - Nigeria'bs leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria
Read more »



Render Time: 2025-04-18 15:03:03