Ṣé Buhari yọ owó kiaramabani àwọn ènìyàn fún díṣù gẹ́gẹ́bí Garba Shehu ṣe wí? | TheCable

Nigeria News News

Ṣé Buhari yọ owó kiaramabani àwọn ènìyàn fún díṣù gẹ́gẹ́bí Garba Shehu ṣe wí? | TheCable
Nigeria Latest News,Nigeria Headlines
  • 📰 thecableng
  • ⏱ Reading Time:
  • 41 sec. here
  • 2 min. at publisher
  • 📊 Quality Score:
  • News: 20%
  • Publisher: 80%

Ṣé MBuhari yọ owó kiaramabani àwọn ènìyàn fún díṣù gẹ́gẹ́bí Garba Shehu ṣe wí? Read full story in Yoruba (Ka ìròyìn l'ẹkunrẹrẹ nínú linki yìí ) 👉🏽

Atẹjade kan ní oṣù kẹsàn-án, ọdún 2013 mẹ́nuba àwọn owó kiaramabani àwọn ènìyàn fún díṣù tí Ọbásanjọ́ yọ.

“Láti inú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn nkan tí a rí kà, Niger Delta jẹ́ ibi tí wíwa epo ní ọ̀nà tí kò yẹ ti ń gbẹrẹgẹjigẹ láti ọdún 2009 tàbí ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2010.

Nígbà tí ó ń sọ ọ̀rọ̀ nípa ọ̀rọ̀ yìí, Jide Pratt, ẹni tí ó ń mojuto ilé-iṣẹ́ tí a mọ̀ sí Cotevis Energy ṣàlàyé pé, botilẹpe Buhari ti yọ owó kiaramabani àwọn ènìyàn ti kẹrosini, wọ́n ti yọ ti díṣù láti ọdún 2003. Amọsa, ó sọ pé iye tí wọ́n fi lé owó díṣù wáyé láti lè jẹ́ kí àwọn ènìyàn máa táà ju iye tí òfin fi ọwọ́ sì.

We have summarized this news so that you can read it quickly. If you are interested in the news, you can read the full text here. Read more:

thecableng /  🏆 2. in NG

Nigeria Latest News, Nigeria Headlines

Similar News:You can also read news stories similar to this one that we have collected from other news sources.

Garba Shehu: Buhari didn't ask Tinubu not to probe his former appointees | TheCableGarba Shehu: Buhari didn't ask Tinubu not to probe his former appointees | TheCableGarba Shehu, ex-spokesperson of former President Muhammadu Buhari, says his principal did not ask his successor not to investigate ministers and aides under the previous administration.
Read more »

'He is allergic to probe' - Shehu Sani mocks Buhari over reported agreement with Tinubu'He is allergic to probe' - Shehu Sani mocks Buhari over reported agreement with TinubuShehu Sani, a socio-political commentator has mocked former President Muhammadu Buhari after he reportedly pleaded not to be probed by his successor. Sani
Read more »

Buhari didn’t ask Tinubu not to investigate him — ShehuBuhari didn’t ask Tinubu not to investigate him — ShehuSpokesperson to former President Muhammadu Buhari, Garba Shehu, on Thursday, denied that the former leader asked his successor not to investigate some ministers under the previous government.
Read more »

Buhari didn’t ask Tinubu not to investigate him — ShehuBuhari didn’t ask Tinubu not to investigate him — ShehuHe also said Buhari had left Daura for London to get some needed rest which, constant visits from well-wishers, had denied him.
Read more »

FACT CHECK: Did Buhari's administration remove diesel subsidy as Garba Shehu claimed? | TheCableFACT CHECK: Did Buhari's administration remove diesel subsidy as Garba Shehu claimed? | TheCableOn Monday, Garba Shehu, ex-spokesperson of former President Muhammadu Buhari, claimed that the last administration removed diesel subsidy. Speaking on why the Buhari administration failed to remove the petrol subsidy
Read more »

Shin gwamnatin Buhari ce ta cire tallafin dizel kamar yadda Garba Shehu ya ce? | TheCableShin gwamnatin Buhari ce ta cire tallafin dizel kamar yadda Garba Shehu ya ce? | TheCableA ranar Litinin, Garba Shehu, tsohon mai magana da yawun tsohon shugaban kasa Muhammadu Buhari, yace gwamnatin data sauka ce ta cire tallafin mai na dizel. Da yake magana akan
Read more »



Render Time: 2025-04-02 19:09:54