Nigeria's independent online newspaper
Àwòrán kan tí àwọn ènìyàn ń pín kiri ní orí ohun ìgbàlódé ìbáraẹnise ti ṣe àfihàn àwọn hẹlikọputa tí àwọn ènìyàn fi rọkẹẹti já lulẹ̀ láti ojú Òfurufú.
Ọ̀rọ̀ tí wọ́n sọ nípa àwòrán náà sọ pé àwọn Hamas, àwọn afipasenkan tí orílẹ̀-èdè Palestine ni ó já àwọn hẹlikọputa náà tí ó jẹ́ ti orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì lulẹ̀ nínú oogun tí ó ń lọ lọ́wọ́ láàárín orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì àti Hamas. “Wọ́n tí ń bá àwọn hẹlikọputa Ísírẹ́lì jẹ́,” báyìí ni atẹsita tí @Sentletse, tí ó ní àwọn olutẹnle ọọdunrun ó dín ní mẹtadinlọgbọn ṣe wí ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù kẹwàá, ọdún 2023.
Àwọn ènìyàn ẹgbẹ̀rún ní ọ̀nà igba àti mẹrinla ni ó ti wòó/ríi ọ̀rọ̀ yìí. Àwọn ènìyàn ẹẹdẹgbẹta dín ní mọ́kànlá ni ó fẹ́ràn rẹ̀, àwọn ènìyàn aadoje ló ti sọ̀rọ̀ nípa ẹ, àwọn ènìyàn marundinlọgọrun ni ó pín in.
Lẹhin ìkọlù náà, àwọn ènìyàn bíi egbèje ni wọ́n pàdánù ẹ̀mí wọn. Àwọn ènìyàn bíi igba ni wọ́n kó sí Àhámọ́.Àwọn afipasenkan Hamas ni ó ń darí ohun tí ó ń lọ ní Gaza. Gaza wà láàárín Ísírẹ́lì àti Mediterranean sea. Gaza sún mọ́ orílẹ̀-èdè Igipiti .
Nigeria Latest News, Nigeria Headlines
Similar News:You can also read news stories similar to this one that we have collected from other news sources.
Why we quickly passed N2.17 trillion supplementary budgetPremium Times - Nigeria'bs leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria
Read more »
Mainz sack El Ghazi after Germany opens probe into posts on Israel-Hamas warBundesliga club Mainz sacked footballer Anwar El Ghazi on Friday, hours after German prosecutors opened an investigation over his social media posts on the Israel-Hamas war.
Read more »
Israel-Hamas war taking away focus from UkraineThe sprawling frontline between the two warring sides has barely moved in almost a year, with one senior Ukrainian official warning this week that the conflict was deadlocked.
Read more »
Fierce Fighting In Gaza As Hamas Accuses Israel Of Killing 30 In Camp BombingFighting continues to rage in densely populated Gaza, despite calls for a ceasefire from Arab countries and desperate civilians after 30 days of war.
Read more »