Nigeria's independent online newspaper
William Ruto, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Kenya láìpẹ́ sọ pé òhun ni olórí Áfíríkà àkọ́kọ́ láti ogún ọdún sí ìgbà yìí tí Ààrẹ Amẹ́ríkà pé láti gbà ní àlejòÓ sọ ọ̀rọ̀ yìí níbi tí Benny Hinn ti ṣe ìyìn rere.
Àwọn ènìyàn ti wo ara ọ̀rọ̀ yi, èyí tí wọ́n gbé jáde lórí Citizen TV ní ọna ẹgbẹ̀rún igba àti ogójì ó dínkan láàárín ọjọ́ mọ́kànlá lórí ohun ìgbàlódé tí àwọn ènìyàn ti ń pín àwòrán nkan tàbí ti ara wọn ti o ni àwọn olùtẹ̀lé mílíọ̀nù...
Ẹni mìíràn kan tí ó ń lo X sọ pé kílóde tí wọ́n ṣe ń sọ̀rọ̀ nípa Amẹ́ríkà tí Ruto fẹ́ lọ níbi ìhìn rere.
Osita Agbu, pròfẹ́sọ̀ nípa bí àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ń bá ara wọn ṣe ní Baze University, ní Nàìjíríà, sọ pé ìgbàlálejò àwọn aṣojú ìjọba àwọn orílẹ̀-èdè kan ní àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn ṣe “pàtàkì gidi gan” nítorí pé ó máa ń fún àwọn aṣojú orílẹ̀-èdè ní...
Nigeria Latest News, Nigeria Headlines
Similar News:You can also read news stories similar to this one that we have collected from other news sources.
Article of Faith: The God who kills before He makes alive, By Femi AribisalaPremium Times - Nigeria'bs leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria
Read more »
CBN reiterates directive to banks on utilisation of forex gainsPremium Times - Nigeria'bs leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria
Read more »
When the Chief Justice brings the judiciary to ridicule, By Chidi Anselm OdinkaluPremium Times - Nigeria'bs leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria
Read more »
Abducted school children may become bandits in future, Group warnsPremium Times - Nigeria'bs leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria
Read more »
Abdul Ningi and the “Apapin” fraternity, By Festus AdedayoPremium Times - Nigeria'bs leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria
Read more »
JUST IN: Give me power to spend security votes like governors, Wike lobbies lawmakersPremium Times - Nigeria'bs leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria
Read more »